- Fifẹ ṣiṣe iranti yii lẹyin awọn irun ọranyan.
- Iranti yii okunfa aforijin ẹṣẹ ni o jẹ.
- Titobi ọla Ọlọhun ti ọla Rẹ ga ati ikẹ Rẹ ati aforijin Rẹ.
- Dajudaju iranti yii okunfa aforijin ẹṣẹ ni, ati pe nkan ti wọn gbero ni: Pipa awọn ẹṣẹ kekere rẹ, ṣugbọn awọn ẹṣẹ nla ko si nkan ti o le pa a rẹ ayaafi ituuba.