- A fẹ́ ki a maa dunni mọ iranti yii lẹyin gbogbo irun ọranyan kọọkan.
- Musulumi a maa ṣe iyanran pẹlu ẹsin rẹ yio si tun maa fi awọn arisami rẹ han koda ki awọn alaigbagbọ korira rẹ.
- Ti gbolohun: “Duburu Sọlaat” ba wa nínú hadiisi, ti nkan ti o wa ninu hadīth yẹn ba jẹ àsíkìrí, ipilẹ rẹ ni ki o jẹ ẹyin salamọ, ti o ba wa jẹ adua, iwaju salamọ ni yio jẹ.