- O n bẹ fun ero ẹyin pẹlu imaamu rẹ ìṣesí mẹẹrin: Wọn kọ kuro nibi mẹta, oun naa ni: Gbigba iwaju ati biba dọgba ati pipẹ lẹyin, ati pe eyi ti wọn ṣe lofin fun ero ẹyin ni: Titẹle imaamu.
- Jijẹ dandan itẹle ero ẹyin fun imaamu rẹ ninu irun.
- Adehun iya pẹlu yiyi aworan ẹni ti o ba gbe ori rẹ soke ṣaaju Imaamu sí aworan Kẹtẹkẹtẹ nkan ti o rọrun ni, oun si wa ninu pipa aworan da.