- Pataki kiki irun daadaa ati mimu awọn origun rẹ wa pẹlu ifarabalẹ ati irẹlẹ.
- Ṣíṣe iroyin ẹni ti ko ba ṣe rukuu rẹ ati iforikanlẹ rẹ laṣepe pẹlu pe ole ni lati leni sá kúrò nibẹ, ati lati tani ji si ṣíṣe e ni eewọ.
- Jijẹ dandan ṣíṣe rukuu ati iforikanlẹ laṣepe nibi irun ati nínà tọ̀ọ̀ lẹ́yìn ti a ba gbori kúrò nibi mejeeji.