- Ṣíṣe Musulumi lojukokoro lori àbójútó irun, ọran-anyan ni ati akigbọrẹ; nitori pe o ko iforikanlẹ sinu.
- Alaye agbọye ẹsin awọn saabe ati imọ wọn pe dajudaju alujanna wọn ko lee wọ ọ- lẹyin ikẹ Ọlọhun- afi pẹlu iṣẹ.
- Iforikanlẹ nibi irun wa ninu eyi ti o tobi julọ ninu awọn okunfa igbe awọn ipo ga, ati aforijin àwọn ẹṣẹ.