- Iwa iṣọra yii ninu awọn adua ti o pataki ti o si kun fọfọ ni, latari pe o ko iwa iṣọra kuro nibi awọn aburu aye ati alukiyaamọ sinu.
- Ririnlẹ iya saare ati pe dajudaju ododo ni i.
- Ewu awọn fitina ati pataki wiwa iranlọwọ pẹlu Ọlọhun ati ṣiṣe adua fun lila kuro ninu rẹ (fitina).
- Fifi jijade dajjāl ati titobi fitina rẹ rinlẹ.
- Ṣiṣe adua yii ni sunnah lẹyin ataaya igbẹyin.
- Ṣiṣe adua ṣiṣe ni sunnah lẹyin iṣẹ oloore.