- Alaye pataki irun ati aimaṣe ọlẹ nibi kiki rẹ ati sisan an padà.
- Lilọ irun lara tayọ asiko rẹ ko lẹtoọ ni ti mọọmọ laini awijare.
- Jijẹ dandan sisan irun pada fun ẹni ti o ba gbagbe ti o ba ti ranti ati ẹni ti o sun ti o ba ti ji.
- Jijẹ dandan sisan awọn irun pada ni yara yara koda ko jẹ awọn asiko ti a ṣe kiki irun ni eewọ nibẹ.