- Titobi ipò Fatiha ati pe Ọlọhun pe e ni (Irun).
- Ṣiṣe alaye iko akolekan Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga- pẹlu ẹru Rẹ, nigba ti o yin in pẹlu okunfa idupẹ rẹ ati ẹyin rẹ ati gbigbe tobi rẹ, O si ṣadehun fun un lati fun un ni nnkan ti o ba beere.
- Surah Alapọn-ọnle yii ko ọpẹ sinu, ati iranti ọrun, ati pipe Ọlọhun, ati imọ ijọsin kanga fun Un, ati ibeere imọna lọ si oju ọna taara, ati ikilọ kuro nibi titọ awọn oju ọna ibajẹ.
- Ìní ìmọ̀lára hadiisi yii fun olukirun- ti o ba ti ka Fatiha- yoo maa ṣe alekun ipaya rẹ lori irun.