- Kikọ awọn ọmọ kekere ni awọn àlámọ̀rí ẹsin siwaju bibalaga, ninu eyi ti o ṣe pataki nibẹ ni irun.
- Nina maa n jẹ nitori kikọ lẹkọọ, ko ki n ṣe tori ifiyajẹ, wọn maa na an ni nina ti o yẹ ẹ́.
- Ikolekan Sharia si sisọ ọmọluwabi, ati kikọdi gbogbo ọna ti o le ja sibi ibajẹ.