- Awọn ẹ̀ṣẹ̀ yẹn, kéékèèké n bẹ ninu wọn, ńlánlá naa sì n bẹ ninu wọn.
- Majẹmu pípa àwọn ẹ̀ṣẹ̀ kéékèèké rẹ́ ni jíjìnnà sí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ńlánlá.
- Awọn ẹ̀ṣẹ̀ nlanla ni àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ti ijiya wà lori rẹ̀ ni aye, tabi ileri ijiya tabi ibinu Ọlọhun wà lori rẹ̀ ní ọ̀run, tàbí ìdẹ́rùbani wà lori rẹ̀, tabi ibidandan Ọlọhun wà lori ẹnití ó ṣe e, gẹgẹ bii ṣìná àti ọtí mímu.