- Ini-ọla-ju-ara-wọn-lọ awọn iṣẹ laarin ara wọn wà nibamu si ifẹ Ọlọ́hun fun wọn.
- Ìṣe Musulumi lojukokoro lori iko akolekan lori awọn iṣẹ ti wọn dara julọ ati eyi ti o dara tẹle e.
- Iyatọ awọn ìdáhùn Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- nipa eyi ti o dara julọ ninu awọn iṣẹ wà ni ibamu si yiyatọ awọn eniyan ati awọn isẹsi wọn, ati eyi ti o pọ julọ ni anfaani fun gbogbo ẹni kọọkan ninu wọn.