- Ijẹ dandan irun janmọọn; nitori pe ṣiṣe ẹdẹ ko le waye ayaafi nibi nkan ti o ba jẹ dandan ti o si tun jẹ tulaasi.
- Gbolohun rẹ: «Fa ajib» fun ẹniti o ba n gbọ ipe ìrun n tọka si ijẹ dandan irun janmọọn; torí pé ìpìlẹ̀ aṣẹ ni ki o maa tumọ si ijẹ dandan.