- Akolekan Isilaamu pẹlu ìmọ́tótó ati imọra.
- Iwẹ jimọ nkan ti wọn fẹ (sunnah) ni ni ti fifẹ ti wọn kanpa mọ fun irun.
- Didarukọ ori bo tiẹ jẹ wipe didarukọ ara maa ko o sinu; lati le ni akolekan pẹlu rẹ ni.
- Iwẹ jẹ dandan fun gbogbo ẹni ti wọn ba ri oorun ti ko daa ti awọn eeyan le maa ri inira pẹlu rẹ ni ara rẹ.
- Ọjọ ti o fi n kanpa julọ fun iwẹ (sunnah) ni ọjọ jimọ; latari ọla rẹ.