- Aanu ati isepele Anọbi - ki ikẹ Olohun ati ola Re maa ba, fún awon ijo rẹ, ati ifoya (ìbẹrù) waala (ìnira) fún àwọn ìjọ rẹ.
- Ìpìlẹ ni pe ti Anọbi pa ṣe - ki ikẹ Olohun ati ola Re máa bá - yoo tumon sí oranyan (dandan) àyaàfi tí ẹrí mi ba wà ti o ntokasi pe a se gbore ni.
- Fife ti a fe ki a run pako ati ọlá rẹ ni gbogbo asiko irun.
- Ibn Daqeeq Al-hiid so bayi pe:
- Ogbon ati oye ti o wa nibi fifẹ ki a run pako nigbati a ba fe lo kirun, ohun ni pe wiwa ni asiko isunmo Olohun, o wa se idajọ ki o je isesi pipe ati imototo, lati se afihan pataki ìjọsìn.
- Akotan (àpapọ) hadith náà se a ko po rirun pako aláwé ko da bi se pe leyin ti o oorun ti kan àtàrí, gégé bí Irun osan (sùúri) ati orun irọlẹ (Àṣẹ) .