- Fifin omi si imu jẹ dandan nibi aluwala, oun ni: Mimu omi wọle sinu imu pẹlu ọna eemi, gẹgẹ bẹẹ naa ni fifin omi síta, oun ni: Mimu omi jade lati inu imu pẹlu ọna eemi.
- Ṣíṣe mimọra pẹlu okuta ni nnkan ti a fẹ ni witiri.
- Ṣíṣe fifọ ọwọ mejeeji lofin lẹyin orun oru lẹẹmẹta.