- Alaye gbigba iwaju Isilaamu ninu awọn ẹkọ ati imọtoto.
- Jijina si awọn nnkan ìdọ̀tí, ti ko ba wa si ibuyẹ afi ki o ṣe e, ki o yaa jẹ pẹlu ọwọ osi.
- Alaye iyi ti o n bẹ fun ọwọ ọtun ati ọla ti o n bẹ fun un lori ọwọ osi.
- Pipe Sharia Isilaamu ati kikun awọn ẹkọ rẹ.