- Ṣisẹnilojukokoro lori ìní akolekan kikọ aluwala ati sunnah rẹ ati awọn ẹkọ rẹ, ati ṣíṣe iṣẹ pẹlu ìyẹn.
- Ọla ti o n bẹ fun aluwala, ati pe o jẹ ipa ẹṣẹ keekeeke rẹ, sugbọn awọn ẹṣẹ ńlá, ironupiwada jẹ dandan lati pa wọn rẹ.
- Majẹmu jijade awọn àṣìṣe ni pipe aluwala ati ṣíṣe e laisi alebu kankan gẹgẹ bi Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ṣe ṣàlàyé rẹ.
- Pipa ẹṣẹ rẹ ninu hadisi yii jẹ nnkan ti a de pẹlu ijina si awọn ẹṣẹ ńlá ati ironupiwada kuro nibẹ, Ọba ti ọla Rẹ ga sọ pé: (Tí ẹ bá jìnnà sí àwọn ẹ̀ṣẹ̀ ńláńlá tí A kọ̀ fun yín, A máa pa àwọn ìwà àìdáa yín rẹ́ fun yín) (An-Nisa: 31).