- Pataki kikọ àwọn ọmọ kéékèèké ni ọrọ ẹsin bii imọ imu-Ọlọhun-lọkan àti àwọn ẹkọ ati nǹkan ti o yatọ si ìyẹn.
- Ẹsan maa wa latara iran iṣẹ.
- Pipaṣẹ igbarale Ọlọhun, ati igbẹkẹle E yatọ si ẹlomiran, Ó sì dára ni Alámòójútó.
- Igbagbọ nínú kádàrá ati yiyọnu si i, ati pe Ọlọhun ni O kádàrá gbogbo nǹkan.
- Ẹni ti o ba ra àṣẹ Ọlọhun lare, Ọlọhun maa ra oun naa lare, ko si nii ṣọ́ ọ.