- Ọlá ti n bẹ fun igbẹkẹle, ati pe o jẹ ọkan ninu awọn ọna ti o tobi julọ ti a fi maa n wa jijẹ-mimu.
- Igbẹkẹle ko tako ṣiṣe awọn okùnfà; tori pe o sọ pe jíjáde ni owurọ ati pípadà ni irọlẹ lati wa jijẹ-mimu ko nii tako igbẹkẹle otitọ.
- Akolekan Sharia si awọn iṣẹ ti awọn ọkan; tori pe ìgbẹ́kẹ̀lé jẹ́ iṣẹ́ àtọkànwá.
- Isomọ awọn okunfa nikan jẹ aipe ninu ẹsin, ti gbigbe awọn okunfa ju silẹ si jẹ aipe ni làákàyè.