- A kii fi òdodo silẹ ni ibẹru ohun ti àwọn èèyàn maa sọ.
- Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ni ikapa ìtọ́sọ́nà ti itọka ati ìjúwe, ṣùgbọ́n ko ni ikapa ìtọ́sọ́nà ti kòńgẹ́.
- Abẹwo Kèfèrí ti o n ṣe aisan lati pe e sinu Isilaamu jẹ nǹkan ti o ba ofin sharia mu.
- Ojúkòkòrò Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- lori ipepe lọ si ọdọ Ọlọhun ti ọla Rẹ ga ni gbogbo iṣesi.