- Ọla ti o n bẹ fun imu Ọlọhun ni Ọkan ati pe ẹni ti o ba ku ni olugbagbọ ododo ti ko da ẹbọ kankan pọ mọ Ọlọhun yoo wọ alujanna.
- Ewu ti o n bẹ fun ẹbọ, ati pe ẹni ti o ba ku ti o n da ẹbọ pọ mọ Ọlọhun yoo wọ ina.
- Àwọn ẹlẹṣẹ nínú awọn ti wọn mu Ọlọhun ni Ọkan ṣoṣo wa ni abẹ fifẹ Ọlọhun ti O ba fẹ yoo fi iya jẹ wọn, ti O ba si fẹ yoo forí jin wọn, lẹyin naa ìkángun wọn maa jẹ alujanna.