- Fifi sisọkalẹ Isa- ki ikẹ Ọlọhun maa ba a- rinlẹ ni igbẹyin ìgbà, ati pe o wa ninu awọn ami ọjọ igbende.
- Sharia Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- eyi ti o yàtọ̀ si i ko lee pa a rẹ.
- Sisọkalẹ awọn alubarika sibi owo ni igbẹyin igba, pẹlu irayesa awọn eniyan nibẹ.
- Iro idunnu pẹlu ṣiṣẹku ẹsin Isilaamu nigba ti Isa- ki ikẹ Ọlọhun maa ba a- maa ṣe idajọ pẹlu rẹ ni igbẹyin igba.