- Ìmúni nífẹ̀ẹ́ láti maa ṣe rere kódà bí ó bá kéré, ati ilenisa kuro nibi ṣiṣe aburu kódà bí ó bá kéré.
- kò sí tabi-ṣugbọn fún musulumi nibi pé kí ó kó irankan ati ìbẹ̀rù papọ ninu aye rẹ̀, kí ó sì maa bẹ Ọlọhun Ọba ni gbogbo igba pé kí Ó mú oun duro sinsin lori ododo títí oun ó fi là, tí iṣesi tí oun wà ò fi nii kó itanjẹ bá oun.