- Idapọ laaarin imọ ati iṣẹ jẹ igbala kuro ni oju ọna awọn ti a binu si ati awọn ẹni anu.
- Ikilọ kuro ni oju ọna awọn Juu ati Nasara, ati didunnimọ oju ọna taara ti o ṣe pe oun ni Isilaamu.
- Olukuluku ninu awọn Juu ati Nasara ni ẹni anu ti a binu si, ṣùgbọ́n eyi ti o jẹ ẹsa ju ninu awọn iroyin awọn Juu ni ibinu, ti eyi ti o jẹ ẹsa ju ninu awọn iroyin awọn Nasara ni anu.