- Eewọ ni ilekoko ati tipátipá ninu gbogbo nkan, kí a sì gbiyanju lati jina si mejeeji ninu ohun gbogbo; paapaa julọ ninu awọn ijọsin wa ati igbe-titobi fun awọn ẹnirere.
- Wíwá lati ṣe ijọsin ati awọn ohun miiran ní pípé jẹ́ nkan dáadáa; ó sì ni lati jẹ́ pẹlu titẹle ofin sharia.
- Wọ́n fẹ́ kí a maa tẹnumọ́ ọ̀rọ̀ pataki, nitori pé Anabi - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a - tún gbolohun yii sọ ni ẹẹmẹta.
- Ìrọ̀rùn ẹ̀sìn Islam ati àilekoko rẹ̀.