- Isẹnilojukokoro lori imọkanga; tori pe Ọlọhun ko nii gba iṣẹ ayafi eyi ti wọn ba fi wa oju-rere Rẹ̀.
- Awọn iṣẹ ti a fi maa n sunmọ Ọlọhun ti O lágbára ti O gbọnngbọn, ti ẹni tí o ti bàlágà ba ṣe e ni ti àṣà, ko nii gba ẹsan titi ti yoo fi gbero isunmọ Ọlọhun pẹlu ẹ.