- Ikilọ kuro nibi ifarawe àwọn keferi ati awọn obilẹjẹ.
- Ṣiṣenilojukokoro lori fifi ara we àwọn ẹni rere ati ikọṣe wọn.
- Ìṣe àfarawé ni gbangba maa n jẹ ki èèyàn nífẹ̀ẹ́ dé inú.
- Ọmọniyan maa tọ́ si àdéhùn ìyà ati ẹṣẹ bi o ba ṣe ṣe àfarawé tó ati irú ìran àfarawé ti o ba ṣe.
- Kikọ afarawe awọn alaigbagbọ ninu ẹsin wọn ati ninu awọn aṣa wọn ti o jẹ ti wọn nìkan ni, ṣùgbọ́n nibi ohun ti ko ba ri bẹẹ, gẹgẹ bii kikọ iṣẹ ṣíṣe àwọn nǹkan ati iru bẹẹ, ko si ninu eewọ naa.