- Ṣiṣenilojukokoro lori ìjúwe lọ sibi oore.
- Igbaniyanju lati ṣe rere jẹ ọkan ninu awọn idi fun iṣọkan àwùjọ Musulumi ati pípé rẹ.
- Fífẹ̀ ọla Ọlọhun.
- Hadiisi naa jẹ òfin kan ti o kari ti gbogbo iṣẹ́ olóore maa ko sinu rẹ.
- Ti ọmọniyan ko ba ni ikapa lati ṣe nǹkan ti ẹni tí n tọrọ nǹkan lọdọ rẹ n fẹ́, o maa júwe ẹlòmíràn fun un.