- Pataki pipaṣẹ daadaa ati kikọ kuro nibi aidaa nibi dida aabo bo awọn awujọ ati lila rẹ.
- Ninu awọn ọna ikọnilẹkọọ ni fifi àkàwé lelẹ, lati fi sun àwọn itumọ mọ ọpọlọ pẹlu aworan ti oju leri.
- Ṣiṣe ibajẹ ti o han pẹlu aikọ kuro nibẹ, aburu ni ti yio mu inira ba gbogboogbo.
- Iparun awujọ n bẹ nibi fifi awọn onibajẹ silẹ ki wọn o maa tan ibajẹ ka orilẹ.
- Ìwà ti kò tọ̀nà ati aniyan daadaa ko to fun didara iṣẹ.
- Ojúṣe ninu àwùjọ Musulumi, ohun apawọpọṣe ni, kii ṣe ohun ti ẹnìkan maa dá ṣe.
- Fifi iya jẹ gbogboogbo pẹlu awọn ẹsẹ awọn kan nigba ti wọn o ba ti ṣe atako.
- Awọn onibajẹ maa n fi ibajẹ wọn han ni aworan daadaa ni awujọ gẹgẹ bi awọn munaafiki ṣe rí.