- O di dandan fún ẹni tí o ba jẹ alaṣẹ lori nnkan kan ninu àlámọ̀rí àwọn Musulumi ki o ṣe pẹ̀lẹ́ pẹ̀lú wọn bi o ba ṣe kápá mọ.
- Ẹsan maa wa latara iran iṣẹ.
- Òṣùwọ̀n ohun ti a maa kà kún ninu ìwà pẹ̀lẹ́ tabi ilekoko ni ohun ti ko ba ti tako Kuraani ati Sunna.