- Ninu awọn itọka ìjẹ́ anabi Anabi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- ni sisọ nnkan ti o maa ṣẹlẹ̀ ninu awọn kọ̀kọ̀ ati ṣiṣẹlẹ rẹ bi o ṣe sọ.
- Iyọnu si ibajẹ ko lẹtọọ tabi kikopa nibẹ, titako o si jẹ dandan.
- Ti awọn adari ba da nnkan ti o tako Sharia silẹ, itẹle wọn nibi ìyẹn ko lẹtọọ.
- Ailẹtọọ jijade si awọn adari Musulumi; nitori nnkan ti o wa ninu ìyẹn ninu ibajẹ ati ita ẹjẹ silẹ ati lílọ ifọkanbalẹ, itẹmọra ibajẹ awọn adari ẹlẹṣẹ, ati ṣíṣe suuru lori suta wọn rọrun ju ìyẹn lọ.
- Irun, ọrọ rẹ tobi, oun ni iyatọ laaarin aigbagbọ ati Isilaamu.