- Kikọ kuro nibi nini awọn aja ati mimaa mu wọn lọ si ibi kan, wọn wa yọ kúrò ninu kikọ yii aja ọdẹ tabi aja oluṣọ.
- Awọn malaika ti wọn o kọ lati wa pẹlu rẹ ni awọn malaika ikẹ, ṣugbọn awọn malaika oluṣọ awọn o ki n ya awọn ẹrusin ni ile ni tabi ni ajo.
- Kikọ kuro nibi agogo; nítorí pé feere kan ni ninu awọn feere satani, o si tun jọ agogo awọn Kristẹni.
- O jẹ dandan fun musulumi ki o jina si gbogbo nkan ti o ba jẹ pe o le maa le awọn malaika jina si i.