- Kikọ kuro nibi kiki irun ni itẹ tabi ni aarin rẹ tabi si i lára ayaafi irun oku gẹgẹ bi o ṣe fi ẹsẹ mulẹ ninu sunnah.
- Kikọ kuro nibi kiki irun si sàréè lati dena ijẹ-atẹgun imu-orogun-mọ Ọlọhun.
- Isilaamu kọ kuro nibi ikọja ààlà nibi awọn sàréè ati kuro nibi yiyẹpẹrẹ rẹ, ko gbọdọ si àṣejù ko si gbọdọ si aseeto.
- Ọwọ Musulumi si ṣẹku lẹyin iku rẹ, latari gbolohun rẹ - ki ikẹ ati ọla Ọlọhun maa ba a – ti o sọ pe: (Rirun eegun oku da gẹgẹ bii rirun un (eegun) ni ààyè ni).