- Dajudaju fífi ibura gbé titobi fún nkan jẹ́ ẹ̀tọ́ fún Ọlọhun Allah, mimọ ni fun Un, nitori naa a kò gbọdọ búra pẹlu nkankan ayafi Ọlọhun ati awọn orukọ Rẹ̀ ati awọn iroyin Rẹ̀.
- Ìtaraṣàṣà awọn Sahabe lori pipaṣẹ rere ati kikọ aburu, paapaa julọ tí aburu naa ba nii ṣe pẹlu ẹbọ tabi aigbagbọ.