- Ẹsan yii maa jẹ ti ẹni tí ó bá wí i ni ojúmọ́ léraléra tabi kélekèle.
- AT-TESBIIH: Oun ni mimọ Ọlọhun kúrò nibi adinku, AL-HAMDU: Oun ni fifi pípé ròyìn rẹ pẹ̀lú ìfẹ́ ati gbigbetobi.
- Ohun ti a gbèrò nibi hadiisi naa ni pipa àwọn ẹṣẹ kéékèèké rẹ, ṣùgbọ́n ẹṣẹ ńlá, dandan ni ki èèyàn tuuba kuro nibẹ.