- Ẹni ti o ba gbe ara le nkan ti o yatọ si Ọlọhun, Ọlọhun a ba a lo pẹlu idakeji erongba rẹ.
- Nini adisọkan pe dajudaju siso agbekọ okunfa fun titi aburu ati ojukoju danu ni jẹ ẹbọ kékeré, ṣugbọn ti o ba ni adisọkan pe o le se anfaani fúnra rẹ, ẹbọ ti o tobi niyẹn.