- Alaye ọla ti o wa fun awọn aayah igbẹyin Sūratul Bakọra, ti o bẹrẹ lati ibi gbolohun Ọlọhun ti ọla Rẹ ga ti o wi pe: (Āmana rosūlu…) titi de ipari Sūrah naa.
- Awọn igbẹyin Sūratul Bakọra maa n ti aidara ati aburu ati èṣù dànù fún ẹni tí o ba n ka a ti o ba ka a ni alẹ.
- Oru bẹrẹ pẹlu wiwọ oorun, o si pari pẹlu yiyọ alufajari.