- Ẹsan maa wa ni ibamu si iṣẹ ni ti odiwọn ati bi iṣẹ ba ṣe rí.
- Ṣiṣenilojukokoro lori kika Kuraani, ati mimu ojú tó o dáadáa, ati hiha a, ati ìrònú jinlẹ nipa rẹ, ati lílo ohun ti o wa ninu ẹ.
- Alujanna ni ọ̀pọ̀lọpọ̀ ìpele ati ipò, onikuraani maa dé ipò ti o ga julọ ninu ẹ.