- Àlàyé iyì Kuraani, ati pe oun ni ọ̀rọ̀ ti o loore ju; tori pe ọ̀rọ̀ Ọlọhun ni.
- Ẹni tí ó ni oore ju ninu awọn akẹ́kọ̀ọ́ ni ẹni tí n kọ́ ẹlòmíràn, kii ṣe ẹni tí ó fi mọ lori ara rẹ nìkan.
- Kíkọ́ Kuraani, ati kikọ ẹlòmíràn ni Kuraani kó kike e ati awọn ìtumọ̀, ati awọn idajọ sinu.