- Àdéhùn ìyà iná fun ẹni ti o ba kọ imọ lati maa ṣe iyanran pẹ̀lú ẹ, tabi ìjiyàn pẹ̀lú ẹ, tabi wiwa ni iwájú nibi àpéjọ pẹ̀lú ẹ, ati bẹẹ bẹẹ lọ.
- Pataki mimọ àníyàn kangá fun ẹni ti o ba kọ́ imọ ti o si tun kọ ẹlòmíràn.
- Aniyan ni ipilẹ àwọn iṣẹ, ori rẹ naa si ni ẹsan maa wa.