- Jijẹ dandan jijẹun pẹlu ọwọ ọtun, ati jijẹ eewọ jijẹun pẹlu ọwọ osi.
- Ṣíṣe igberaga nibi titẹle awọn ofin Sharia maa n mu ẹni ti o ba ṣe lẹtọọ si iya.
- Apọnle Ọlọhun fun Anabi Rẹ- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- pẹlu gbigba adura rẹ.
- Ṣíṣe pipaṣẹ pẹlu daadaa lofin ati kikọ kuro nibi ibajẹ ni gbogbo isẹsi koda nibi isẹsi jijẹ.