- Títa ọrẹ Ọlọhun ti O lágbára ti O gbọnngbọn, O fúnni ni arisiki, O si yọnu si idupẹ.
- Eeyan le ri iyọnu Ọlọhun ni ọ̀nà ti o rọrun jùlọ, gẹgẹ bii ṣíṣe ALHAMDULILLAAH lẹ́yìn jijẹ ati mimu.
- Ninu ẹkọ oúnjẹ ati nǹkan mimu ni: Idupẹ fun Ọlọhun lẹyin jijẹ ati mimu.