- Ṣíṣe yiya aworan nǹkan abẹ̀mí ni eewọ; tori pe o wa ninu awọn àtẹ̀gùn lọ síbi ẹbọ.
- Mímú ohun buruku kuro pẹ̀lú ọwọ fun ẹni ti o ba ni àṣẹ tabi agbára lati ṣe bẹ́ẹ̀ jẹ nǹkan ti o ba sharia mu.
- Ojúkòkòrò Anọbi- ki ikẹ Ọlọhun ati ọla Rẹ maa ba a- lori mimu gbogbo nǹkan ti o ba n tọka si oripa àsìkò aimọkan kúrò, bíi àwọn àwòrán ati awọn ère, ati awọn nǹkan ti wọn mọ sórí sàréè.