- Titobi ẹtọ ti aládùúgbò ati ọranyan lati ṣe akiyesi iyẹn.
- Títẹnu mọ́ ẹ̀tọ́ aládùúgbò pẹ̀lú àsọtẹ́lẹ̀ n béèrè fun pé kí a bọ̀wọ̀ fún un, ki a wa ki o nífẹ̀ẹ́ ẹni, ki a si ṣe daadaa si i, ki a si ma jẹ ki o ri ìpalára, ki a si maa bẹ ẹ wo ti o ba ṣe àìsàn, ki a si maa ki i nígbà ìdùnnú, ki a si ba a kẹ́dùn nígbà àjálù.
- Bí ẹnu-ọ̀nà aládùúgbò bá ṣe sunmọ si, bẹ́ẹ̀ náà ni ẹ̀tọ́ rẹ̀ ṣe maa kanpá sí.
- Pípé sharia nibi nǹkan ti o mu wa ninu nǹkan ti didara àwùjọ wa nínú ẹ, bii ṣíṣe dáadáa si awọn aládùúgbò, ati titi ìpalára kuro fun wọn.