- Isilaamu o le pe ayaafi pẹlu àìfi ṣuta kan ẹlòmíràn, o jẹ èyí tí a fi oju ri ni abi èyí tí a o le ni ìmọ̀lára rẹ.
- Wọn ṣa ahọn ati ọwọ lẹsa pẹlu didarukọ wọn; latari pipọ awọn aṣiṣe wọn ati awọn inira wọn, ati pe dajudaju ọdọ wọn ni ọpọlọpọ aburu ti maa n wa.
- Ṣiṣenilojukokoro lori gbigbe awọn ẹṣẹ silẹ ati ṣíṣe nkan ti Ọlọhun ti ọla Rẹ ga pa lasẹ.
- Ẹni ti o ni ọla julọ ninu awọn musulumi ni ẹni ti o pe awọn iwọ Ọlọhun ati awọn iwọ awọn musulumi.
- Itayọ aala le jẹ ọrọ tabi iṣe.
- Hijrah ti o pe oun ni yiyan nkan ti Ọlọhun ti ọla Rẹ ga ṣe ni eewọ lodi.