- Ṣisẹnilojukokoro lori iran-ara-ẹni-lọwọ ati ikun-ara-ẹni-lọwọ ati didi bukaata awọn ọlẹ.
- Ijọsin ko gbogbo iṣẹ oloore sínú, ati pe ninu ijọsin ni riran awọn opo ati alaini lọwọ wa.
- Ibnu Hubairọ sọ pe: Nnkan ti a gba lero ni pe dajudaju Ọlọhun- ti ọla Rẹ ga- maa ko ẹsan alaawẹ ati eni ti o n dide loru ati olujagun fun un lẹẹkan naa; ìyẹn rí bẹ́ẹ̀ nitori pe o duro sipo ọkọ fun opo...., o si duro ti alaini yẹn ti ko lee da duro fun ara rẹ, eleyii si na nǹkan ti o le si nǹkan ti o bukaata si, o si ṣe saara pẹlu igbiyanju rẹ, nitori naa anfaani rẹ wa ṣe deedee awẹ ati didide ati igbiyanju soju ọna Ọlọhun.