- Ṣiṣeni ni ojukokoro lori lilo iṣẹmi s'ibi nkan ti yio yọ Ọlọhun ti ọla Rẹ ga ninu.
- Awọn idẹra Ọlọhun pọ lori awọn ẹru, ati pe yio bi i leere nipa idẹra eleyii ti o wa ninu rẹ, nitori naa o jẹ dandan fun un ki o gbe awọn idẹra Ọlọhun sí ibi tí yio yọ Ọ ninu.