- Ohun ti o ba n ṣe idiwọ fun ẹ lati ṣe rere, a kii pe e ni ituju, ohun ti a maa n pe e ni ìdójútì, ati ikagara, ati ọ̀lẹ, ati ojo.
- Ìtìjú Ọlọhun ti O lágbára ti O gbọnngbọn naa ni ki èèyàn maa ṣe ohun ti O pàṣẹ rẹ, ki èèyàn si fi àwọn nǹkan eewọ silẹ.
- Ìtìjú ẹ̀dá naa ni ṣíṣe apọnle wọn, ki èèyàn si fi wọn si ipo wọn, ki èèyàn si jìnà si ohun ti o ba buru ni ti àṣà.