- Ọlá ti n bẹ fun deede ati ṣiṣenilojukokoro lori rẹ.
- Deede kari gbogbo ìjọba ati idajọ láàrin àwọn èèyàn, titi dórí deede laarin awọn ìyàwó, ati awọn ọmọ, ati bẹẹ bẹẹ lọ.
- Ṣíṣe àlàyé ipò àwọn onideede ni ọjọ igbende.
- Yiyatọ ipò àwọn onigbagbọ si ara wọn ni ọjọ́ igbende, onikaluku ni ibamu si iṣẹ rẹ ni.
- Ọ̀nà ṣiṣenilojukokoro wa ninu awọn ọ̀nà ipepe ti maa n jẹ ki o wu ẹni tí a n pè lati tẹle ti Ọlọhun.