- Àánú Ọlọhun ti O lágbára ti O gbọnngbọn si ẹ̀dá.
- Pipa ati didu nǹkan dáadáa pẹ̀lú ki o jẹ ọ̀nà ti o ba òfin mu.
- Pípé ṣẹria ati kiko ti o ko gbogbo oore sinu, ninu ìyẹn ni àánú ẹranko ati ṣíṣe pẹ̀lẹ́ pẹ̀lú ẹ.
- Kíkọ̀ kúrò nibi ifi ìyà jẹ ènìyàn lẹ́yìn pípa a.
- Ṣiṣe gbogbo nnkan ti ìjìyà ba n bẹ nibẹ fun ẹranko ni eewọ.